Main Article Content
Àgbéye ̩̀ wò orísirísi ìlò èdè tí ó jè̩ yò̩ nínú ìwé ìtàn àròsọ kò sọ́rọ̀tí layọ̀ ògúnlọlá kọ
Abstract
Ìlò èdè Yorùbá láàrin àwọn ọmọ káàárò-̣oò-jíire tí n di ohun àfìṣéỵ ìn tí éégún n fisọ. Ìdí gan nìyí tí olùwádìí ṣe gùnlé kókó iṣé ̣yìí láti ṣe àwárí àwọn àkànlò èdè ayàwòrán tó forí nù jáde ní pàápàá jùlọ nínú ìwé Ìtàn Àròsọ Kò Sóṛò.̣ Iṣé ̣ yìí ṣe àwárí àwọn àkànlò-èdè bíi ìyán-òṛò-̣féṛé,̣ ìṣewéḳ ú, ìfìrógbòyeyọ, ìfìrómọrísì, ìfìrósínrójẹ, ìfohùnpènìyàn, òwe, ìfènìyànpohun àti àfiwé tààrà. Iṣé ̣ àpilèḳ ọ yìí ṣe àgbéyèẉ ò àwọn ìlò èdè wòṇ yí nípa lílo tíóṛì soṣíóḷój̣ì lítíréṣò ̣tó tèḷé èrò Karl Marx. Ní ìparí, iṣé ̣yìí dábàá fún àwọn akéḳ òọ́ ̣tó n kó ̣èḳ ó ̣Yorùbá, àwọn olùfé ̣èdè Yorùbá, àwọn ilé iṣé ̣rédíò àti tẹlifísàn tí ń gbé èdè Yorùbá lárugẹ láti máa ṣe àmúlò àwọn àkànlò èdè ayàwòrán wòṇ yí nínú ìgbòkègbodò wọn lójoojúmó,̣ nípa síṣe èyí, èdè wa kò ní lọ sí oko ìparun.



