Main Article Content
Òwe Yorùbá Ge ǵ̣ e ̣́bí Àpẹẹrẹ Ọnà-èdè Alátinúdá Ajẹme ẉ́ à: Kò Gbọdo ̣́Ku Provérbios iorubás como exemplo de linguagem criativa: ela não deve morrer
Abstract
Iṣẹ́ ̣́ àpile ḳ́ ọ yìí ṣe àgbéye ẉ́ ò òwe èdè Yorùbá tó jẹ mọ́ ̣́ e ḳ́ ọ́ ̣́ ilé àti ìpe ṭ́ùsááwo ̣́ láwùjọ Yorùbá. Yorùbá gbà pé òwe jẹ́ ̣́ o ḳ́ an lára àwọn ọnà-èdè ajẹmẹ́ẉ́ à alátinúdá èyí tó jẹ́ ̣́ orísun ìmo ̣́ e ḳ́ ọ́-̣́ ilé àti ìpe ṭ́ùsááwo .̣́ Èdè Yorùbá jẹ́ ̣́o ḳ́ an lára èdè abínibí ní Nàìjíríà tí ó ní olùsọ mílío ṇ́ ù ọgbọ̀́n. Wọ́ṇ́ tún ń sọ ọ́ ̣́ ní Benin, Togo, Siera-Leone, Brazil, Cuba, Trinidad àti Tobago, Amẹ́ṛ́ íkà abbl. Ó jẹ́ ̣́ èdè olóhùn tó ní ìhun Olùwà-O ̣́ro -̣́ ìṣe-Àbo ̣́ (Subject-Verb-Object). Ó jẹ́ ̣́ e ỵ́ à ìpín èdè Benue Congo titun. Àmúlò òwe láwùjọ lóde òní kò dàbí ti àtijọ́ ̣́ mọ́ .̣́ Àwọn àgbàlagbà tí wọ́ṇ́ máa ń pa òwe nípase ̣́ ìrírí wọn ti ń dínkù. Àwa o ḍ́ ọ́ ̣́tí a sì wà kò ní ìrírí tó jinle ̣́tí ó sì lè mú kí a máa pa òwe láwùjọ. O ̣́po ̣́àwọn o ḍ́ ọ́ ̣́ tí a fo ṛ́ o ̣́ wá lẹ́ṇ́ u wò nípa ìmo ̣́ wọn nínú òwe pípa ní pàtàkì èyí tó jẹ mọ́ ̣́ e ḳ́ ọ́-̣́ ilé àti ìpe ṭ́ùsááwo ̣́ ni wọ́ṇ́ kùnà. Ìpèníjà lèyí, tó ń wá àmójútó ní kíákíá. Ìdí nìyí tí a fi dáwọ́ ̣́ lé iṣẹ́ ̣́ ìwádìí yìí, kí á lè wá ojútùú sí ìṣòro yìí, kí àwọn òwe wa má ba kú. Tíọ́ṛ́ ì ìbára-ẹni-gbé-po -̣́ láwùjọ àti ti ìpe ṭ́ùsááwo ̣́ ni a mú lò nínú iṣẹ́ ̣́ yìí. Ọgbọ́ṇ́ ìwádìí tí a mú lò fún àkójọpo ̣́ èdè fáye ẉ́ ò ni títọ àwọn olùsọ èdè yìí tí ọjọ́ ̣́ orí wọn be ṛ́ e ̣́ láti àádọ́ ṭ́a sí ọgọ́ṛ́ in lọ fún oríṣiríṣi òwe àti àmúlò wọn. A wo àwọn ìwé àti iṣẹ̣́́ àpile ḳ́ ọ lórí òwe wò. A wo orí e ṛ́ ọ ayélujára bákan náà. Àbájáde iṣẹ́ ̣́ yìí jẹ́ ̣́ ká ní ìmo ̣́ nípa oríṣiríṣi àwọn òwe Yorùbá bó ti ṣe kan e ḳ́ ọ́-̣́ ilé àti ìpe ṭ́ùsááwo .̣́ Ó wúlò fún kíkọ́ ̣́ ọmọ ní ìwà ọmọlúwàbí èyí tó máa ń ṣe ìgbélárugẹ àṣà, ìṣe àti ìgbàgbọ́ ̣́àwọn Yorùbá, tó sì ń yọrí sí ìbára-ẹni-gbé-po ̣́alálàáfíà. Nínú iṣẹ́ ̣́ yìí, a wo oríkì, e ḍ́ á káríayé àti ìwúlò òwe ní pàtàkì òwe fún e ḳ́ ọ́-̣́ ilé àti ti ìpe ṭ́ùsááwo .̣́ A wo “Yorùbá” gẹ́ǵ̣ ẹ́ ̣́ bí o ṇ́ à ìbániso ṛ́ o ̣́ àti àwọn e ỵ́ à kan. Òwe mú kí àyípadà dé bá àwùjọ sí rere. Ipa tó ń kó nínú ìpe ṭ́ùsááwo ̣́ láwùjọ kò kéré. Àwọn ìwúlò wo ṇ́ yí ni òwe kò fi gbọ́ḍ́ o ̣́kú.
Este artigo examina os provérbios iorubás relacionados à educação doméstica e à reconciliação na sociedade iorubá. Os iorubás acreditam que os provérbios são uma das artes da linguagem criativa, fonte de conhecimento sobre educação doméstica e reconciliação. O iorubá é uma das línguas indígenas da Nigéria, com trinta milhões de falantes. Também é falado no Benim, Togo, Serra Leoa, Brasil, Cuba, Trinidad e Tobago, Estados Unidos, etc. É uma língua tonal com estrutura sujeito-verbo-objeto. É um novo dialeto benue-congo. O uso de provérbios na sociedade atual não é o mesmo do passado. O número de adultos que usam provérbios com base em suas experiências está diminuindo. Nós, jovens, não temos a experiência profunda que nos leva a usar provérbios na sociedade. Muitos jovens que entrevistamos sobre seu conhecimento de provérbios, especialmente aqueles relacionados à educação doméstica e ao perdão, fracassaram. Este é um desafio que precisa de atenção urgente. É por isso que empreendemos este projeto de pesquisa, para encontrar uma solução para este problema, para que nossos provérbios não morram. A teoria da interação social e do perdão foi utilizada neste trabalho. O método de pesquisa utilizado para a coleta de dados foi entrevistar falantes dessa língua, com idades entre cinquenta e oitenta anos, para vários provérbios e seus usos. Analisamos livros e artigos sobre provérbios. Também consultamos a internet. Os resultados deste trabalho nos deram conhecimento sobre vários provérbios iorubás relacionados à educação doméstica e à reconciliação. Eles são úteis para ensinar às crianças boas maneiras que promovem a cultura, os costumes e as crenças iorubás, e levam à coexistência pacífica. Neste trabalho, examinamos a poesia, o mundo e os usos dos provérbios, especialmente aqueles para a educação doméstica e a reconciliação. O "iorubá" é visto como um meio de comunicação e um meio de comunicação entre certas tribos. Os provérbios trazem mudanças positivas na sociedade. Seu papel na reconciliação social não é pequeno. Esses são os usos que os provérbios não devem ser esquecidos.



